1. Ṣe o ni ikọ-wara?
2. Ṣe o ni otutu?
3. Njẹ o n ya igbẹ gbuuru?
4. Ṣe o ni ọfun ọgbẹ?
5. Njẹ o ni iriri MYALGIA tabi Ara Riro?
6. Ṣe ori n fọ ẹ?
7. Ṣe o ni iba?
8. Ṣe o ni iṣoro eemi?
9. Ṣe o n ni iriri rirẹ?
10. Njẹ o rin irin ajo laipẹ ni awọn ọjọ mẹrinla sẹhin?
11. Ṣe o ni itan irin-ajo si eyikeyi orilẹ-ede to ni COVID-19?
12. Ṣe o n duro si ayika taara tabi o n tọju ẹni to ni COVID-19?